damnlyrics.com

Etulese

Etun le se jube lo o bese se lojosi leti okun pupa..

omi tu jade lati inu apata..baba etun se lekan

si....kale soro ogo re larin awon keferi kale royin ise

iyanu larin gbogbo eniyan...nitori te tobi o ju orisha

lo....(choros)baba jewo ara re karaye lemo wipeee

ire nikan loba....araye mawun bere eniyan mawun

bere wonsowipe ogo atijo nko we wonna won in d

palace of hope

Lyrics Submitted by akinloye akintunde

Enjoy the lyrics !!!