damnlyrics.com

Halleluyah

Hallelujah ni won ma ko

Hallelujah si wo olurun mi

Orin hallelujah ni woo bawon torun ko oOju orun fun dede

Awo San man ni Pele ni pele

Eru lo fi ko aye

Okun fun ajara

Eda o yanbo Awo

Ewo lo da Ara oto to

MO korin hallelujah si wo tan awon

Orun bo o

againMimo Mimo ni won ke

Awon ti Eda orun angeli lowo lowoo

Won fi ojo jo fi ori bale o

Agba gba n ke Mimo

Si oludande aye gbogbo

Hallelujah si oni ite ogo aditu

Gbogboro owo to na aye ja lati inu orun wa Kikorin won o dake ri

Si olurun awon omo ogunagain

Hallelujah ni won ko

Won segun aye ko si daru dapo

Owun gbo lo Leto leto

Ebi ko pa won ri beeni Ara ko ni won ri

Kida ayo ekunrere alafia

Awa ti a le ke hallelujah ninu aye

Awa lafi Orin isegun se wa logo

A o Jeri Ota a di Eni ite mole pata

Orin hallelujah ni a fi ba Jesu joba

Awa ti a gbalaagain

Song Discussions is protected by U.S. Patent 9401941. Other patents pending.

Enjoy the lyrics !!!