damnlyrics.com

Happy Day

Eki messiah araye

Global salvation lo ma n mu wa

Sanmori tewe tagba e ma ba n ka lo

Ewa gbo nosia yi o e

Opon ori ti sun kan jesu olugbala

Atun gbe salvation de o

Nipa se Adamu ati Efa ewi kin gbo

Gbo gbo aye lo de ru ese, eru iku

Awon omo isreali kepe oluwa lo jo si

Oran Mose lo tu won sile loko eru

Orisirisi wooli, oba ati adajo

gbiyanju titi ko change se lo le koko

Egun nla ni n keyin igbale

lodifa fun bibi jesu olugbala omo araye

Ebami gbe lo ni oyinbo o, komi aro sem sem sem

Oh happy day

Oh happy day...

When jesus washed

When jesus washed

He washed my sins away

Oh happy day

Oh happy day

Everybody rise and dance

Rise and dance, rise and dance, rise and rise and dance...

Opon ori ti sun kan jesu olugbala

Atun gbe salvation de o

Iku oro ti m ba ku, iya ese ti m baje, gbogbo re lo ti ko lo, jesu oluwa o ma se o, to ri mi lo se jiya

Res: Iku oro ti m ba ku, iya ese ti m baje, gbogbo re lo ti ko lo, jesu oluwa o ma se o, to ri mi lo se jiya.

Eki mesiah araye.

Global salvation lo ma n muwa

Etun bami gbe lo ni oyinbo o

Ko mi a ro sem sem sem

All: He taught me how, to watch, watch and pray

Watch and pray

And live rejoicing, every day, every day

How to live, how to live rejoicing

Res: Every day

Call: Global salvation

Lo ma n muwa

International salvation

Lo ma n mu wa

Lo ni repete

Lo ma n mu wa

Lo ni jaburata

Lo ma n mu wa

Jesu ko re daale

Lo ma n mu muwa

Ko wa sha ti e

Lo ma n mu wa

Ilekun orun ti shi

Lo ma n muwa

E ni o wole, ko wole o

Lo ma n muwa

Lo ni repete

Lo ma n muwa

Iwosan re daale

Lo ma n muwa

Iye re ma ni le

Lo ma n muwa (Till fade)

Lyrics Submitted by Pappy

Enjoy the lyrics !!!