damnlyrics.com

Ikoko Akufo (Lamentation For a Broken Pot)

Ikoko Akufo (Lamentation For A Broken Pot) / Beautiful Nubia

Ikoko akufo, o

D'ero akitan o

Ikoko to fo o, o ti dero akitan o

Monomono ya lu'gi, oro wo 'nu ilu o

Itiju bi aso akisa lo ma ri o

O d'oro agbagba o, o d'eru f'ologbon

O d'owo awon agba o, o d'eru f'ologbon

Ilu Orita o, ilu alaafia

Mo ni t'e ba de'be, e ba mi ki won o

Gbogbo wa la o f'ayo de 'le

Mo ni t'e ba ri o, e ba nk'

Awero yen o

Omoge awelewa to nda ni l'orun o

Ile owo ni o wo s'aya

Ile ola ni o wo s'aya o

Seb'ade ori oko ni won, obinrin to n'iwa t'o l'ewa

Iwuri obi ni won o ma je, mobinrin to gb'eko to mu lo

Ori re dara, ori re sunwon, o d'adufe olori oko

Ori re dara, ori re sunwon, o d'abefe o... Ikoko to fo i s'oun

A mu se'be

Ikoko to fo i s'oun a mu to'le

Ikoko to fo i s'oun a mu r'odo

Ikoko to fo i s'oun a mu yan'gan

Ibadi aran d'eni a mu se yeye o

Bi eye ti o l'apa

Ibadi aran d'eni a mu se yeye o

O ba ma i lo o

O ba ma i lo o

Duro se'un obinrin nse

Gb'aye se'un obinrin nse

Lyrics Submitted by Winnie

Enjoy the lyrics !!!