damnlyrics.com

Pansaga Ranti Ojo Ola

Pansaga ranti ojo ola o, pansaga ranti ojo ola oje ronu e wo ko tuba

Awón to dara ju e kini won pin, gbogbo awón to dara ju e kini won pin, Iwo na awo latest, Iwo na awo latest nigati o ba kala oju mo nso, awón to ngun e bi eshin, ti o ba or won, won a mo e loju.

Lyrics Submitted by Matimiloju Olalekan

Enjoy the lyrics !!!