damnlyrics.com

Satani Deyin Lehin Mi

Chorus

Olorun igbala Mo sa di ọ̀ o

Olorun iwosan, Mo sa di ọ̀ o baba

Dina Mo emi okunkun ma je Kan le bori Okan mi o

Agbara satani ati Omo Ogun re ma ni Ko d'asan

Ba satani wi laye mi, edumare Mo be o ye

Ma Se je ki satani raye wonu Okan mi

Mo fi ejo mi to o wa, Jesus saanu fun mi

Mo fi ejo mi to o wa, Jesu gba Oro mi ro

Bi emi okunkun ba parapo, to ba wa Fi ejo mi sun o, ti eje re ni ki o ro baba, Ko Fi da mi lare.

Sanballati nbe laye, Tobiah nbe, Iran Judasi Ko tan laye, ni se lo ye ka funra x2

Ero buburu ti Hamaani gba lori Mordecai, gbogbo re lo d'asan, ise Oluwa ni

Ero buburu ti Hamaani ro lori Mordecai, gbogbo re lo d'asan igbega lo yori si.

Bi emi okunkun ba parapo to ba wa Fi ejo mi sun ọ̀ o, ti eje re ni k'oro Baba, Ko fi da mi lare.

To ri na,chorus

Ibi esu ba go si, mo ni, ninu Ile mi o

Ibi esu ba go si, a ni, ninu ise mi o, agbara n'o ma si, Baba fi ro ojo ina le lori

Ibi esu ba go si, ninu Ile mi o baba

Ibi esu ba go si, a ni,ninu ise mi o, agbara lo ma fi, Baba ro ojo ina le lori

Satani, Oluwa ba o wi dehin leyin mi, a, dehin, dehin, satani dehin leyin mi o dehin

Oluwa lo ba o wi pe ko dehin leyin mi

Eyin iranse satani e dehin leyin mi logo o

E Fi mi sile kin ji se ti Baba ran mi sinu aye o

Se bi Oluwa lo ran mi nise o Ko ma n se eniyan

To ba je eniyan, eniyan o ba ti wo ile ola pa le tipe tipe

Be o ba dehin logo ma fi Oro yin lo Jesu Baba mi

Bi a ba le ni ti a ba ni, ni se la n pada o

Eyin Ogun orun mimo e parapo ki e wa gbe mi mi ja o x2

Oluwa lo ba o wi pe Ko dehin leyin mi satani

Oluwa lo ran mi nise o, Ko ma n se eniyan

E Fi mi sile kin jise ti Baba ran mi

Mo loluwa lo ran mi nise o ki ma nse eniyan

E Fi mi sile kin jise ti Baba ran mi sinu aye o

Ti a ba le ni ti a ba ni, ni se la n pada o

Eyin Ogun orun mimo e parapo ki e wa gbe mi ni ja o.

Lyrics Submitted by Seyi Nwoseh

Enjoy the lyrics !!!