damnlyrics.com

Webake

Mimo lale

Awon irawo won tan

Ojo ale tabi olugbala

Aye kunfun ese ati iparun

Igbatode lafi mu eyi re

Ileri ayo,, ninu aye otosi yi

Igba otun dey,, atojo ologo

Chorus : wole ni ekun re

Gbo ohun enu angeli ko

Ojo iyanu

Ojo iyanu, nigbata bi christi

Ojo ijanu oooo

Ojo iyanu nla

Lotito loun ko wa lati fi ife han

Ofi ife ati iyin rere

Oja ide, eru sidi ore wa

Loruko re, itura yio ba wa

Orin iyin opin lao ma ko oo

Pelu gbogbo o ko leo ma yin

Jesu ni oluwa

Lao ma yin o titi

Ojo o,, ojo o

Ojo iyanu

Iyanu nla

Oh ojo iyanuuuuuuuu.,,,,,,,,,

Ojo iyanu nla

Lyrics Submitted by Seun

Enjoy the lyrics !!!