Awé - Asa
Page format: |
Awé Lyrics
Awe I bo lo lo ka
Ta n fi wao ka
Ibi o ba lo je a mo
Anti to n gbe le I to si
O wa o wa le yi
Ati o jo meta atabo
O wi kpe o, o
O loyun fun o
Oyun oshu meji
Oloyun fun o
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Anti ton loyun fun o
O to bi e l'omo
I wo iwo na
Anti to loyun fun o
O to bi e l'omo, o bi 'mo oh oh
O bi 'mo Ire lo ni mu, ese
Irun ori,iwo dudu
Omo kpu pa ba wo lo se ri
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Ewa wo ja la a fin
Oba ejigbo atabo, atako
Wan ja la fin oba La fin oba.
Wahidi omo muyina ni
Omo sekina
O foju mi ri mabo
Mabo ni le,mabo loko mabo l'eko
Mama to bi mama re
Ni mama mi, emi na bi te mi
Moo ntomo lowo f'omo loyon
Ma ko tire bami
Abo oro lan so f'omo Luabi
To ba de nu re a do n di n di
Din din
---
Lyrics powered by lyrics.tancode.com
written by ASUQUO/ELEMIDE
Lyrics © Sony/ATV Music Publishing LLC