Page format: Left Center Right
Direct link:
BB code:
Embed:

Kinihun De Lyrics


Ọ'rọ' nla tòun gbe inu ọ'rọ'
Ọ'rọ' tó fi ọ'rọ' jade
Ọ'rọ' baba ọ'rọ'
Ọ'rọ'loyun ọ'rọ' bi ọ'rọ'
Ọ'rọ' kanka
Ọ'rọ' tòun gbe inu ọmọ eniyan fohun
Latete ko ṣe l'ọ'rọ' ti wa
Ọ'rọ' wa pelu Ọlọ'run, Ọlọ'run si ni ọ'rọ' naa
Kinihun de, eya Judah
O de... O de
Kinihun de, eya Judah
O de... O de
Alágbára bí ara
O de... O de
Alágbára bí ara
O de... O de
O de... O de

Oba Aládé wúrà de
Kinihun de (o deee) eya Judah
O de... O de (O de ooo)
Kinihun de, eya Judah
O de... O de (O de t'ola t'ola oo togo togo oo)
Alágbára bi ara...
Alágbára bi ara (O de t'ola t'ola)
O de... O de (O de t'ogo t'ogo)
Kiki ogo . kiki ọlá. kiki agbára
O de O de (o de t'ola t'ola o de t'ogo t'ogo)
Kinihun de, eya Judah
O de... O de
Kinihun de, eya Judah
Ó de... O de
Alágbára bí ara
Ó de... O de
Alágbára bí ara
O de... O de
Ó de... O de
Oba Aládé wúrà de
O de... O de
Oba Aládé wúrà de
Ọlọ'run ogo toun gbe inu ogo
Ọlọ'run ogo
Ola le wo láṣọ (ogo oo)
Ogo l'aso ileke
Oba ògo (Ọlọ'run ògo)
You dwell in glory (toun gbe inu ogo)
Ọba àwọn ọba, Oluwa àwọn Olúwa
Ola le wo l'aso
Ògo l'aso ileke (Ọlọ'run ògo)
Koseni tale fi o wee èé (toun gbe inu ogo)
... (Ọlọ'run ogo, ogo oooo)
There's none like you
You're the matchless king (Ọlọ'run ògo)
Great Saviour (toun gbe inu ogo)
Awesome Father (Ọlọ'run ogo ogo ooo)
Lyrics Submitted by Saula Adetunji Gift

Enjoy the lyrics !!!

More lyrics by Adewale Mary Jane, Dapo Omidiora & Glt Music